Léfítíkù 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀+ pẹ̀lú àwọn aṣọ,+ òróró àfiyanni,+ akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, àgbò méjì àti apẹ̀rẹ̀ búrẹ́dì aláìwú,+ Hébérù 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí gbogbo àlùfáà àgbà tí a mú láàárín àwọn èèyàn ni a yàn nítorí wọn láti bójú tó àwọn ohun tó jẹ mọ́ Ọlọ́run,+ kó lè fi àwọn ọrẹ àti ẹbọ rúbọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀.+
2 “Mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀+ pẹ̀lú àwọn aṣọ,+ òróró àfiyanni,+ akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, àgbò méjì àti apẹ̀rẹ̀ búrẹ́dì aláìwú,+
5 Torí gbogbo àlùfáà àgbà tí a mú láàárín àwọn èèyàn ni a yàn nítorí wọn láti bójú tó àwọn ohun tó jẹ mọ́ Ọlọ́run,+ kó lè fi àwọn ọrẹ àti ẹbọ rúbọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀.+