Ẹ́kísódù 38:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àwọn nǹkan yìí ni wọ́n kà pé ó wà nínú àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ Ẹ̀rí.+ Mósè ló pàṣẹ pé kí àwọn ọmọ Léfì+ kà á, kí Ítámárì ọmọ àlùfáà Áárónì sì darí wọn.+ Léfítíkù 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Mósè fara balẹ̀ wá ewúrẹ́ tí wọ́n fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ náà, ó sì rí i pé wọ́n ti sun ún. Ni inú bá bí i sí Élíásárì àti Ítámárì, àwọn ọmọ Áárónì yòókù, ó sì sọ pé: 1 Kíróníkà 24:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nádábù àti Ábíhù kú ṣáájú bàbá wọn,+ wọn ò sì ní ọmọkùnrin kankan; àmọ́ Élíásárì+ àti Ítámárì ń ṣiṣẹ́ àlùfáà nìṣó.
21 Àwọn nǹkan yìí ni wọ́n kà pé ó wà nínú àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ Ẹ̀rí.+ Mósè ló pàṣẹ pé kí àwọn ọmọ Léfì+ kà á, kí Ítámárì ọmọ àlùfáà Áárónì sì darí wọn.+
16 Mósè fara balẹ̀ wá ewúrẹ́ tí wọ́n fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ náà, ó sì rí i pé wọ́n ti sun ún. Ni inú bá bí i sí Élíásárì àti Ítámárì, àwọn ọmọ Áárónì yòókù, ó sì sọ pé:
2 Nádábù àti Ábíhù kú ṣáájú bàbá wọn,+ wọn ò sì ní ọmọkùnrin kankan; àmọ́ Élíásárì+ àti Ítámárì ń ṣiṣẹ́ àlùfáà nìṣó.