-
Ẹ́kísódù 39:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Lẹ́yìn náà, wọ́n lẹ òkúta ónísì mọ́ orí ìtẹ́lẹ̀ wúrà, wọ́n sì fín orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì sára rẹ̀, bí ìgbà tí wọ́n fín nǹkan sára èdìdì.+
-
-
Ẹ́kísódù 39:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àwọn òkúta náà dúró fún orúkọ ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì méjìlá (12), wọ́n sì fín àwọn orúkọ náà sára òkúta bí èdìdì, orúkọ kọ̀ọ̀kan dúró fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ẹ̀yà méjìlá (12) náà.
-