Léfítíkù 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mósè mú àwọn ọmọ Áárónì sún mọ́ tòsí, ó wọ aṣọ fún wọn, ó so ọ̀já mọ́ wọn lára, ó sì wé* aṣọ sí wọn lórí,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.
13 Mósè mú àwọn ọmọ Áárónì sún mọ́ tòsí, ó wọ aṣọ fún wọn, ó so ọ̀já mọ́ wọn lára, ó sì wé* aṣọ sí wọn lórí,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.