Léfítíkù 8:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ó mú búrẹ́dì aláìwú kan tó rí bí òrùka,+ búrẹ́dì kan tí wọ́n fi òróró sí tó rí bí òrùka+ àti búrẹ́dì pẹlẹbẹ kan látinú apẹ̀rẹ̀ búrẹ́dì aláìwú tó wà níwájú Jèhófà. Ó sì kó wọn sórí àwọn ọ̀rá náà àti ẹsẹ̀ ọ̀tún.
26 Ó mú búrẹ́dì aláìwú kan tó rí bí òrùka,+ búrẹ́dì kan tí wọ́n fi òróró sí tó rí bí òrùka+ àti búrẹ́dì pẹlẹbẹ kan látinú apẹ̀rẹ̀ búrẹ́dì aláìwú tó wà níwájú Jèhófà. Ó sì kó wọn sórí àwọn ọ̀rá náà àti ẹsẹ̀ ọ̀tún.