8 Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ tó mọṣẹ́+ mú aṣọ mẹ́wàá tó jẹ́ aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa, tí wọ́n fi ń pa àgọ́, pẹ̀lú fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù àti òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò, wọ́n sì fi ṣe àgọ́ ìjọsìn;+ ó kó iṣẹ́ sí wọn lára, iṣẹ́ náà jẹ́ àwòrán àwọn kérúbù.+