Diutarónómì 9:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nígbà náà, mo rí i pé ẹ ti ṣẹ Jèhófà Ọlọ́run yín! Ẹ ti ṣe ọmọ màlúù onírin* fún ara yín. Ẹ ti yára kúrò ní ọ̀nà tí Jèhófà pa láṣẹ pé kí ẹ máa rìn.+ 17 Mo bá mú wàláà méjèèjì, mo fi ọwọ́ mi méjèèjì là á mọ́lẹ̀, mo sì fọ́ ọ túútúú níṣojú yín.+
16 Nígbà náà, mo rí i pé ẹ ti ṣẹ Jèhófà Ọlọ́run yín! Ẹ ti ṣe ọmọ màlúù onírin* fún ara yín. Ẹ ti yára kúrò ní ọ̀nà tí Jèhófà pa láṣẹ pé kí ẹ máa rìn.+ 17 Mo bá mú wàláà méjèèjì, mo fi ọwọ́ mi méjèèjì là á mọ́lẹ̀, mo sì fọ́ ọ túútúú níṣojú yín.+