Ẹ́kísódù 32:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Gbàrà tí Mósè sún mọ́ àgọ́ náà, tó sì rí ère ọmọ màlúù+ àtàwọn tó ń jó, inú bí Mósè gan-an, ó ju àwọn wàláà náà sílẹ̀, ó sì fọ́ wọn túútúú sí ẹsẹ̀ òkè náà.+
19 Gbàrà tí Mósè sún mọ́ àgọ́ náà, tó sì rí ère ọmọ màlúù+ àtàwọn tó ń jó, inú bí Mósè gan-an, ó ju àwọn wàláà náà sílẹ̀, ó sì fọ́ wọn túútúú sí ẹsẹ̀ òkè náà.+