ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 24:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Àmọ́ tó bá dà bíi pé ó burú lójú yín láti máa sin Jèhófà, ẹ fúnra yín yan ẹni tí ẹ fẹ́ máa sìn lónìí,+ bóyá àwọn ọlọ́run tí àwọn baba ńlá yín sìn ní òdìkejì Odò*+ tàbí àwọn ọlọ́run àwọn Ámórì tí ẹ̀ ń gbé ní ilẹ̀ wọn.+ Ṣùgbọ́n ní tèmi àti agbo ilé mi, Jèhófà ni àwa yóò máa sìn.”

  • 2 Àwọn Ọba 10:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Bó ṣe kúrò níbẹ̀, ó bá Jèhónádábù+ ọmọ Rékábù+ pàdé tó ń bọ̀ wá bá a. Nígbà tó kí i,* ó sọ fún un pé: “Ṣé gbogbo ọkàn rẹ wà* pẹ̀lú mi bí ọkàn mi ṣe wà pẹ̀lú ọkàn rẹ?”

      Jèhónádábù fèsì pé: “Bẹ́ẹ̀ ni.”

      Jéhù wá sọ pé: “Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, fún mi ní ọwọ́ rẹ.”

      Torí náà, ó na ọwọ́ sí i, Jéhù sì fà á gòkè sínú kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́