Ẹ́kísódù 17:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ni Mósè bá sọ fún Jóṣúà+ pé: “Bá wa yan àwọn ọkùnrin, kí o sì lọ bá àwọn ọmọ Ámálékì jà. Ní ọ̀la, màá dúró sórí òkè, màá sì mú ọ̀pá Ọlọ́run tòótọ́ dání.” Ẹ́kísódù 24:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mósè gbéra pẹ̀lú Jóṣúà ìránṣẹ́ rẹ̀,+ Mósè sì lọ sórí òkè Ọlọ́run tòótọ́.+
9 Ni Mósè bá sọ fún Jóṣúà+ pé: “Bá wa yan àwọn ọkùnrin, kí o sì lọ bá àwọn ọmọ Ámálékì jà. Ní ọ̀la, màá dúró sórí òkè, màá sì mú ọ̀pá Ọlọ́run tòótọ́ dání.”