Ẹ́kísódù 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mo ti máa ń fara han Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù pé èmi ni Ọlọ́run Olódùmarè,+ àmọ́ ní ti orúkọ mi Jèhófà,+ mi ò jẹ́ kí wọ́n fi mọ̀ mí.+ Ẹ́kísódù 33:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ Ọlọ́run dáhùn pé: “Màá mú kí gbogbo oore mi kọjá níwájú rẹ, màá sì kéde orúkọ Jèhófà níwájú rẹ;+ èmi yóò ṣojúure sí ẹni tí èmi yóò ṣojúure sí, èmi yóò sì ṣàánú ẹni tí èmi yóò ṣàánú.”+
3 Mo ti máa ń fara han Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù pé èmi ni Ọlọ́run Olódùmarè,+ àmọ́ ní ti orúkọ mi Jèhófà,+ mi ò jẹ́ kí wọ́n fi mọ̀ mí.+
19 Àmọ́ Ọlọ́run dáhùn pé: “Màá mú kí gbogbo oore mi kọjá níwájú rẹ, màá sì kéde orúkọ Jèhófà níwájú rẹ;+ èmi yóò ṣojúure sí ẹni tí èmi yóò ṣojúure sí, èmi yóò sì ṣàánú ẹni tí èmi yóò ṣàánú.”+