Ẹ́kísódù 33:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Báwo ni àwọn èèyàn yóò ṣe mọ̀ pé èmi àti àwọn èèyàn rẹ ti rí ojúure rẹ? Ṣebí tí o bá bá wa lọ ni,+ kí èmi àti àwọn èèyàn rẹ lè yàtọ̀ sí gbogbo èèyàn yòókù tó wà ní ayé?”+ Diutarónómì 10:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Òun ni Ẹni tí wàá máa yìn.+ Òun ni Ọlọ́run rẹ, tó ṣe gbogbo ohun àgbàyanu àtàwọn ohun tó ń dẹ́rù bani yìí fún ọ, tí o sì fi ojú ara rẹ rí i.+
16 Báwo ni àwọn èèyàn yóò ṣe mọ̀ pé èmi àti àwọn èèyàn rẹ ti rí ojúure rẹ? Ṣebí tí o bá bá wa lọ ni,+ kí èmi àti àwọn èèyàn rẹ lè yàtọ̀ sí gbogbo èèyàn yòókù tó wà ní ayé?”+
21 Òun ni Ẹni tí wàá máa yìn.+ Òun ni Ọlọ́run rẹ, tó ṣe gbogbo ohun àgbàyanu àtàwọn ohun tó ń dẹ́rù bani yìí fún ọ, tí o sì fi ojú ara rẹ rí i.+