Jóṣúà 24:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Jóṣúà wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ ò lè sin Jèhófà, torí pé Ọlọ́run mímọ́ ni;+ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo ni.+ Kò ní dárí àwọn ìṣìnà* àtàwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín.+
19 Jóṣúà wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ ò lè sin Jèhófà, torí pé Ọlọ́run mímọ́ ni;+ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo ni.+ Kò ní dárí àwọn ìṣìnà* àtàwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín.+