Léfítíkù 19:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Sọ fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Kí ẹ jẹ́ mímọ́, torí èmi Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.+ Sáàmù 99:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ gbé Jèhófà Ọlọ́run wa ga,+ kí ẹ sì forí balẹ̀* níbi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀;+Ẹni mímọ́ ni.+ Àìsáyà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọ̀kan sì ń sọ fún èkejì pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+ Ògo rẹ̀ kún gbogbo ayé.” 1 Pétérù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 àmọ́ bíi ti Ẹni Mímọ́ tó pè yín, kí ẹ̀yin náà di mímọ́ nínú gbogbo ìwà yín,+
2 “Sọ fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Kí ẹ jẹ́ mímọ́, torí èmi Jèhófà Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.+
3 Ọ̀kan sì ń sọ fún èkejì pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+ Ògo rẹ̀ kún gbogbo ayé.”