Ẹ́kísódù 25:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọrẹ tí ẹ máa gbà lọ́wọ́ wọn nìyí: wúrà,+ fàdákà,+ bàbà,+ Ẹ́kísódù 25:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 òróró fìtílà,+ òróró básámù tí wọ́n á fi ṣe òróró àfiyanni+ àti tùràrí onílọ́fínńdà,+