Ẹ́kísódù 40:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ìkùukùu* sì bẹ̀rẹ̀ sí í bo àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+