Jẹ́nẹ́sísì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́ Ébẹ́lì mú lára àwọn àkọ́bí ẹran+ rẹ̀ wá, pẹ̀lú ọ̀rá wọn. Jèhófà ṣojúure sí Ébẹ́lì, ó sì gba ọrẹ+ rẹ̀,
4 Àmọ́ Ébẹ́lì mú lára àwọn àkọ́bí ẹran+ rẹ̀ wá, pẹ̀lú ọ̀rá wọn. Jèhófà ṣojúure sí Ébẹ́lì, ó sì gba ọrẹ+ rẹ̀,