Nọ́ńbà 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ọkùnrin tàbí obìnrin kan bá dá èyíkéyìí nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tí àwọn èèyàn ń dá, tó sì hùwà àìṣòótọ́ sí Jèhófà, ẹni* náà ti jẹ̀bi.+
6 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Tí ọkùnrin tàbí obìnrin kan bá dá èyíkéyìí nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tí àwọn èèyàn ń dá, tó sì hùwà àìṣòótọ́ sí Jèhófà, ẹni* náà ti jẹ̀bi.+