ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 28:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 “Kí o fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa hun aṣọ tó ní bátànì igun mẹ́rin, kí o sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe láwàní, kí o sì hun ọ̀já.+

  • Léfítíkù 16:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 “Kí àlùfáà tí ẹ fòróró yàn,+ tí ẹ fiṣẹ́ lé lọ́wọ́* láti ṣe àlùfáà+ dípò bàbá rẹ̀+ ṣe ètùtù, kó sì wọ aṣọ ọ̀gbọ̀,+ aṣọ mímọ́.+

  • Ìsíkíẹ́lì 44:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “‘Tí wọ́n bá wá sí àwọn ẹnubodè àgbàlá inú, kí wọ́n wọ aṣọ ọ̀gbọ̀.*+ Wọn ò gbọ́dọ̀ wọ aṣọ kankan tí wọ́n fi irun àgùntàn ṣe nígbà tí wọ́n bá ń ṣiṣẹ́ ní àwọn ẹnubodè àgbàlá inú tàbí tí wọ́n bá wọlé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́