Ẹ́kísódù 27:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí o ṣe àwọn garawa láti máa fi kó eérú* rẹ̀ dà nù, kí o tún ṣe àwọn ṣọ́bìrì, àwọn abọ́, àwọn àmúga àti àwọn ìkóná, bàbà sì ni kí o fi ṣe gbogbo ohun èlò rẹ̀.+ Léfítíkù 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kó yọ àpò oúnjẹ ẹyẹ náà, kó tu àwọn ìyẹ́ rẹ̀, kó sì jù wọ́n sẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ lápá ìlà oòrùn, níbi tí eérú*+ wà.
3 Kí o ṣe àwọn garawa láti máa fi kó eérú* rẹ̀ dà nù, kí o tún ṣe àwọn ṣọ́bìrì, àwọn abọ́, àwọn àmúga àti àwọn ìkóná, bàbà sì ni kí o fi ṣe gbogbo ohun èlò rẹ̀.+
16 Kó yọ àpò oúnjẹ ẹyẹ náà, kó tu àwọn ìyẹ́ rẹ̀, kó sì jù wọ́n sẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ lápá ìlà oòrùn, níbi tí eérú*+ wà.