-
Léfítíkù 1:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Kí wọ́n pa á ní apá àríwá pẹpẹ níwájú Jèhófà, kí àwọn ọmọ Áárónì, tí wọ́n jẹ́ àlùfáà, sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sí gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ.+
-