Léfítíkù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* sọ̀rọ̀, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Tí ẹnikẹ́ni nínú yín bá fẹ́ fi ẹran ọ̀sìn ṣe ọrẹ fún Jèhófà, kó mú ọrẹ rẹ̀ wá látinú ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran.+
2 “Bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* sọ̀rọ̀, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Tí ẹnikẹ́ni nínú yín bá fẹ́ fi ẹran ọ̀sìn ṣe ọrẹ fún Jèhófà, kó mú ọrẹ rẹ̀ wá látinú ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran.+