Ẹ́kísódù 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Gbàrà tí Áárónì bá gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ tán, wọ́n yíjú pa dà, wọ́n sì dojú kọ aginjù. Wò ó! ògo Jèhófà fara hàn nínú ìkùukùu.*+ Ẹ́kísódù 24:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ògo Jèhófà+ ò kúrò lórí Òkè Sínáì,+ ìkùukùu náà sì bò ó fún ọjọ́ mẹ́fà. Ní ọjọ́ keje, ó pe Mósè látinú ìkùukùu náà. Ẹ́kísódù 40:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ìkùukùu* sì bẹ̀rẹ̀ sí í bo àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+
10 Gbàrà tí Áárónì bá gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ tán, wọ́n yíjú pa dà, wọ́n sì dojú kọ aginjù. Wò ó! ògo Jèhófà fara hàn nínú ìkùukùu.*+
16 Ògo Jèhófà+ ò kúrò lórí Òkè Sínáì,+ ìkùukùu náà sì bò ó fún ọjọ́ mẹ́fà. Ní ọjọ́ keje, ó pe Mósè látinú ìkùukùu náà.