ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hébérù 5:1-3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Torí gbogbo àlùfáà àgbà tí a mú láàárín àwọn èèyàn ni a yàn nítorí wọn láti bójú tó àwọn ohun tó jẹ mọ́ Ọlọ́run,+ kó lè fi àwọn ọrẹ àti ẹbọ rúbọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀.+ 2 Ó ṣeé ṣe fún un láti ṣàánú àwọn aláìmọ̀kan* àti àwọn tó ń ṣàṣìṣe,* torí òun náà ní àìlera tiẹ̀,* 3 ìdí nìyẹn tí òun náà fi gbọ́dọ̀ rú ẹbọ nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tiẹ̀, bó ṣe ń ṣe nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn gẹ́lẹ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́