Léfítíkù 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mósè wá sọ fún Áárónì pé: “Sún mọ́ pẹpẹ, kí o rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ rẹ àti ẹbọ sísun, kí o sì ṣe ètùtù fún ara rẹ+ àti ilé rẹ; mú ọrẹ àwọn èèyàn náà wá,+ kí o sì ṣe ètùtù fún wọn,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ.” Léfítíkù 16:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Kí Áárónì mú akọ màlúù ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wá, èyí tó jẹ́ tirẹ̀, kó sì ṣe ètùtù torí ara rẹ̀+ àti ilé rẹ̀.
7 Mósè wá sọ fún Áárónì pé: “Sún mọ́ pẹpẹ, kí o rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ rẹ àti ẹbọ sísun, kí o sì ṣe ètùtù fún ara rẹ+ àti ilé rẹ; mú ọrẹ àwọn èèyàn náà wá,+ kí o sì ṣe ètùtù fún wọn,+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ.”