ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 18:38, 39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Ni iná Jèhófà bá bọ́ láti òkè, ó sì jó ẹran ẹbọ sísun+ náà àti àwọn igi, àwọn òkúta àti iyẹ̀pẹ̀ ibẹ̀ run, ó sì lá omi inú kòtò náà gbẹ.+ 39 Nígbà tí gbogbo àwọn èèyàn náà rí i, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ wọ́n dojú bolẹ̀, wọ́n sì sọ pé: “Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́! Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́!”

  • 2 Kíróníkà 7:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Gbàrà tí Sólómọ́nì parí àdúrà rẹ̀,+ iná bọ́ láti ọ̀run,+ ó jó ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ náà, ògo Jèhófà sì kún ilé náà.+

  • 2 Kíróníkà 7:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Gbogbo àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ń wò nígbà tí iná bọ́ sílẹ̀, tí ògo Jèhófà sì bo ilé náà, wọ́n tẹrí ba, wọ́n sì dojú bolẹ̀ lórí ibi tí a fi òkúta tẹ́, wọ́n wólẹ̀, wọ́n sì dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà, “nítorí ó jẹ́ ẹni rere; ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ sì wà títí láé.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́