8 “Tí àrùn ẹ̀tẹ̀* bá yọ, kí ẹ rí i pé ẹ ṣe gbogbo ohun tí àwọn àlùfáà tó jẹ́ ọmọ Léfì bá ní kí ẹ ṣe.+ Kí ẹ rí i pé ẹ ṣe ohun tí mo pa láṣẹ fún wọn gẹ́lẹ́.
23 “‘Kí wọ́n fún àwọn èèyàn mi ní ìtọ́ni nípa ìyàtọ̀ tó wà láàárín ohun tó mọ́ àti ohun yẹpẹrẹ; wọ́n á sì kọ́ wọn ní ìyàtọ̀ tó wà láàárín ohun tí kò mọ́ àti ohun tó mọ́.+