ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 2:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “‘Tí ẹnì* kan bá fẹ́ mú ọrẹ ọkà+ wá fún Jèhófà, kó jẹ́ ìyẹ̀fun tó kúnná, kó da òróró sórí rẹ̀, kó sì fi oje igi tùràrí sórí rẹ̀.+

  • Léfítíkù 14:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Ní ọjọ́ kẹjọ, kó mú ọmọ àgbò méjì tí ara wọn dá ṣáṣá, abo ọ̀dọ́ àgùntàn+ ọlọ́dún kan tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá, kó mú ìyẹ̀fun tó kúnná tí wọ́n pò mọ́ òróró tó jẹ́ ìdá mẹ́ta nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà* láti fi ṣe ọrẹ ọkà+ àti òróró tó kún òṣùwọ̀n lọ́ọ̀gì kan;*+

  • Nọ́ńbà 15:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 kí ẹni tó ń mú ọrẹ rẹ̀ wá fún Jèhófà tún mú ọrẹ ọkà wá, kó jẹ́ ìyẹ̀fun tó kúnná+ tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà,* tó pò mọ́ òróró ìlàrin òṣùwọ̀n hínì.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́