ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 14:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ní ọjọ́ keje, kó fá gbogbo irun orí rẹ̀ àti àgbọ̀n rẹ̀ àti irun ojú rẹ̀. Tó bá ti fá gbogbo irun rẹ̀, kó fọ aṣọ rẹ̀, kó fi omi wẹ̀, yóò sì di mímọ́.

  • Máàkù 1:44
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 44 ó sọ fún un pé: “Rí i pé o ò sọ nǹkan kan fún ẹnikẹ́ni, àmọ́ lọ fi ara rẹ han àlùfáà, kí o sì mú àwọn ohun tí Mósè sọ dání láti wẹ̀ ọ́ mọ́,+ kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.”+

  • Lúùkù 5:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ó wá pàṣẹ fún ọkùnrin náà pé kó má sọ fún ẹnikẹ́ni, ó ní: “Àmọ́ lọ, kí o fi ara rẹ han àlùfáà, kí o sì ṣe ọrẹ láti wẹ̀ ọ́ mọ́, bí Mósè ṣe sọ,+ kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.”+

  • Lúùkù 17:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nígbà tó rí wọn, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ fi ara yín han àwọn àlùfáà.”+ Bí wọ́n ṣe ń lọ, ara wọn mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́