4 Jésù wá sọ fún un pé: “Rí i pé o ò sọ fún ẹnì kankan,+ àmọ́ lọ, kí o fi ara rẹ han àlùfáà,+ kí o sì mú ẹ̀bùn tí Mósè sọ lọ,+ kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.”
14 Ó wá pàṣẹ fún ọkùnrin náà pé kó má sọ fún ẹnikẹ́ni, ó ní: “Àmọ́ lọ, kí o fi ara rẹ han àlùfáà, kí o sì ṣe ọrẹ láti wẹ̀ ọ́ mọ́, bí Mósè ṣe sọ,+ kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.”+