ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 14:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Kí àlùfáà lọ sí ẹ̀yìn ibùdó, kó sì yẹ̀ ẹ́ wò. Tí àrùn ẹ̀tẹ̀ náà bá ti lọ lára adẹ́tẹ̀ náà, 4 kí àlùfáà pàṣẹ pé kó mú ààyè ẹyẹ méjì tó mọ́ wá, pẹ̀lú igi kédárì, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti ewéko hísópù láti fi wẹ̀ ẹ́ mọ́.+

  • Léfítíkù 14:19, 20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “Kí àlùfáà rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀+ náà, kó sì ṣe ètùtù fún ẹni tó fẹ́ wẹ ara rẹ̀ mọ́ kúrò nínú àìmọ́ rẹ̀, lẹ́yìn náà, kó pa ẹran ẹbọ sísun. 20 Kí àlùfáà sun ẹran ẹbọ sísun àti ọrẹ ọkà+ lórí pẹpẹ, kí àlùfáà sì ṣe ètùtù fún un,+ yóò sì di mímọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́