Mátíù 8:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jésù wá sọ fún un pé: “Rí i pé o ò sọ fún ẹnì kankan,+ àmọ́ lọ, kí o fi ara rẹ han àlùfáà,+ kí o sì mú ẹ̀bùn tí Mósè sọ lọ,+ kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.”
4 Jésù wá sọ fún un pé: “Rí i pé o ò sọ fún ẹnì kankan,+ àmọ́ lọ, kí o fi ara rẹ han àlùfáà,+ kí o sì mú ẹ̀bùn tí Mósè sọ lọ,+ kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.”