Léfítíkù 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Tí nǹkan kan bá lé sí ara* ẹnì kan, tó sé èépá tàbí tí awọ ara rẹ̀ yọ àbààwọ́n, tó sì lè yọrí sí àrùn ẹ̀tẹ̀*+ ní awọ ara rẹ̀, kí wọ́n mú un wá sọ́dọ̀ àlùfáà Áárónì tàbí ọ̀kan lára àwọn ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà.+
2 “Tí nǹkan kan bá lé sí ara* ẹnì kan, tó sé èépá tàbí tí awọ ara rẹ̀ yọ àbààwọ́n, tó sì lè yọrí sí àrùn ẹ̀tẹ̀*+ ní awọ ara rẹ̀, kí wọ́n mú un wá sọ́dọ̀ àlùfáà Áárónì tàbí ọ̀kan lára àwọn ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà.+