-
Léfítíkù 16:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Kí Áárónì ṣẹ́ kèké lórí ewúrẹ́ méjèèjì, kèké kan fún Jèhófà, kèké kejì fún Ásásélì.*
-
-
Léfítíkù 16:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ kó mú ewúrẹ́ tí kèké mú fún Ásásélì wá láàyè láti dúró níwájú Jèhófà kó lè ṣe ètùtù lórí rẹ̀, kó sì rán an lọ sínú aginjù+ fún Ásásélì.
-