Léfítíkù 23:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Sábáàtì ló jẹ́ fún yín, ọjọ́ ìsinmi tí ẹ ò ní ṣiṣẹ́ rárá, kí ẹ sì pọ́n ara yín* lójú+ ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹsàn-án oṣù. Láti ìrọ̀lẹ́ dé ìrọ̀lẹ́ ni kí ẹ máa pa sábáàtì yín mọ́.”
32 Sábáàtì ló jẹ́ fún yín, ọjọ́ ìsinmi tí ẹ ò ní ṣiṣẹ́ rárá, kí ẹ sì pọ́n ara yín* lójú+ ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹsàn-án oṣù. Láti ìrọ̀lẹ́ dé ìrọ̀lẹ́ ni kí ẹ máa pa sábáàtì yín mọ́.”