ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 3:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 “‘Tí ohun tó mú wá bá jẹ́ ẹbọ ìrẹ́pọ̀,*+ tó sì jẹ́ látinú ọ̀wọ́ ẹran ló ti fẹ́ mú un wá, yálà akọ tàbí abo, ẹran tí ara rẹ̀ dá ṣáṣá ni kó mú wá fún Jèhófà. 2 Kó gbé ọwọ́ lé orí ẹran tó mú wá, kí wọ́n pa á ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé; kí àwọn ọmọ Áárónì, àwọn àlùfáà, sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sí gbogbo ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ.

  • Léfítíkù 7:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 “‘Òfin ẹbọ ìrẹ́pọ̀+ tí ẹnì kan bá mú wá fún Jèhófà nìyí:

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́