Ẹ́kísódù 23:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ẹ ò gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún àwọn ọlọ́run wọn, ẹ má sì jẹ́ kí wọ́n mú kí ẹ sìn wọ́n, ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ohun tí wọ́n ń ṣe.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ṣe ni kí ẹ wó wọn palẹ̀, kí ẹ sì run àwọn ọwọ̀n òrìṣà wọn.+ Léfítíkù 20:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé àṣẹ àwọn orílẹ̀-èdè tí màá lé jáde kúrò níwájú yín;+ torí wọ́n ti ṣe gbogbo nǹkan yìí, mo sì kórìíra wọn.+
24 Ẹ ò gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún àwọn ọlọ́run wọn, ẹ má sì jẹ́ kí wọ́n mú kí ẹ sìn wọ́n, ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe àwọn ohun tí wọ́n ń ṣe.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, ṣe ni kí ẹ wó wọn palẹ̀, kí ẹ sì run àwọn ọwọ̀n òrìṣà wọn.+
23 Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé àṣẹ àwọn orílẹ̀-èdè tí màá lé jáde kúrò níwájú yín;+ torí wọ́n ti ṣe gbogbo nǹkan yìí, mo sì kórìíra wọn.+