ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 6:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Tí ẹnì* kan bá ṣẹ̀, tó hùwà àìṣòótọ́ sí Jèhófà+ torí pé ó tan ọmọnìkejì rẹ̀ jẹ nípa ohun kan tó fi sí ìkáwọ́ rẹ̀ tàbí ohun kan tó fi pa mọ́ sọ́wọ́ rẹ̀+ tàbí tó ja ọmọnìkejì rẹ̀ lólè tàbí tó lù ú ní jìbìtì,

  • Òwe 12:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ètè tó ń parọ́ jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+

      Àmọ́ àwọn tó ń fi òtítọ́ hùwà ń mú inú rẹ̀ dùn.

  • Éfésù 4:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Torí náà, ní báyìí tí ẹ ti fi ẹ̀tàn sílẹ̀, kí kálukú yín máa bá ọmọnìkejì rẹ̀ sọ òtítọ́,+ nítorí ẹ̀yà ara kan náà ni wá.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́