Òwe 22:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Má ja tálákà lólè torí pé kò ní lọ́wọ́,+Má sì fojú aláìní gbolẹ̀ ní ẹnubodè,+