Sáàmù 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà, ta ló lè jẹ́ àlejò nínú àgọ́ rẹ? Ta ló lè máa gbé ní òkè mímọ́ rẹ?+ Sáàmù 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kò fi ahọ́n rẹ̀ bani jẹ́,+Kò ṣe ohun búburú kankan sí ọmọnìkejì rẹ̀,+Kò sì ba àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ lórúkọ jẹ́.*+
3 Kò fi ahọ́n rẹ̀ bani jẹ́,+Kò ṣe ohun búburú kankan sí ọmọnìkejì rẹ̀,+Kò sì ba àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ lórúkọ jẹ́.*+