Òwe 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹni tó bá ń fojú àbùkù wo ọmọnìkejì rẹ̀ ń dẹ́ṣẹ̀,Àmọ́ ẹni tó bá ń ṣàánú aláìní jẹ́ aláyọ̀.+ Róòmù 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ má ṣe fi ibi san ibi fún ẹnikẹ́ni.+ Ẹ jẹ́ kí ìrònú yín dá lé ohun tó dára lójú gbogbo èèyàn.