Léfítíkù 20:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “‘Ẹ gbọ́dọ̀ pa ọkùnrin tàbí obìnrin èyíkéyìí tó jẹ́ abẹ́mìílò tàbí woṣẹ́woṣẹ́.*+ Kí àwọn èèyàn sọ wọ́n lókùúta pa. Ẹ̀jẹ̀ wọn wà lórí wọn.’” Ìṣe 16:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ó ṣẹlẹ̀ pé nígbà tí à ń lọ síbi àdúrà, ìránṣẹ́bìnrin kan tó ní ẹ̀mí kan, ẹ̀mí èṣù ìwoṣẹ́,+ pàdé wa. Ó máa ń fi iṣẹ́ wíwò* mú èrè púpọ̀ wá fún àwọn ọ̀gá rẹ̀.
27 “‘Ẹ gbọ́dọ̀ pa ọkùnrin tàbí obìnrin èyíkéyìí tó jẹ́ abẹ́mìílò tàbí woṣẹ́woṣẹ́.*+ Kí àwọn èèyàn sọ wọ́n lókùúta pa. Ẹ̀jẹ̀ wọn wà lórí wọn.’”
16 Ó ṣẹlẹ̀ pé nígbà tí à ń lọ síbi àdúrà, ìránṣẹ́bìnrin kan tó ní ẹ̀mí kan, ẹ̀mí èṣù ìwoṣẹ́,+ pàdé wa. Ó máa ń fi iṣẹ́ wíwò* mú èrè púpọ̀ wá fún àwọn ọ̀gá rẹ̀.