Léfítíkù 19:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “‘Ẹ má tọ àwọn abẹ́mìílò lọ.+ Ẹ má sì wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ àwọn woṣẹ́woṣẹ́,+ kí wọ́n má bàa sọ yín di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín. Léfítíkù 20:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “‘Ní ti ẹni tó bá tọ àwọn abẹ́mìílò+ lọ àti àwọn woṣẹ́woṣẹ́+ kó lè bá wọn ṣe àgbèrè ẹ̀sìn, ó dájú pé màá bínú sí onítọ̀hún,* màá sì pa á, kí n lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.+
31 “‘Ẹ má tọ àwọn abẹ́mìílò lọ.+ Ẹ má sì wádìí ọ̀rọ̀ lọ́wọ́ àwọn woṣẹ́woṣẹ́,+ kí wọ́n má bàa sọ yín di aláìmọ́. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.
6 “‘Ní ti ẹni tó bá tọ àwọn abẹ́mìílò+ lọ àti àwọn woṣẹ́woṣẹ́+ kó lè bá wọn ṣe àgbèrè ẹ̀sìn, ó dájú pé màá bínú sí onítọ̀hún,* màá sì pa á, kí n lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.+