Léfítíkù 11:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ẹ má fi ẹ̀dá èyíkéyìí tó ń gbá yìn-ìn kó ìríra bá ara yín,* ẹ má fi wọ́n kó èérí bá ara yín, kí ẹ má bàa di aláìmọ́.+
43 Ẹ má fi ẹ̀dá èyíkéyìí tó ń gbá yìn-ìn kó ìríra bá ara yín,* ẹ má fi wọ́n kó èérí bá ara yín, kí ẹ má bàa di aláìmọ́.+