25 Kí ẹ fi ìyàtọ̀ sáàárín ẹranko tó mọ́ àti èyí tó jẹ́ aláìmọ́ àti sáàárín ẹyẹ tó jẹ́ aláìmọ́ àti èyí tó mọ́;+ ẹ ò gbọ́dọ̀ sọ ara yín* di ohun ìríra nípasẹ̀ ẹranko tàbí ẹyẹ tàbí ohunkóhun tó ń rákò lórí ilẹ̀ tí mo yà sọ́tọ̀ pé ó jẹ́ aláìmọ́ fún yín.+