ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 28:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 “Kí o fi ògidì wúrà ṣe irin pẹlẹbẹ tó ń dán, kí o sì fín ọ̀rọ̀ yìí sára rẹ̀ bí ẹni fín èdìdì, pé: ‘Ìjẹ́mímọ́ jẹ́ ti Jèhófà.’+

  • Léfítíkù 11:45
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 45 Torí èmi ni Jèhófà, tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì láti jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run,+ ẹ gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́,+ torí èmi jẹ́ mímọ́.+

  • Léfítíkù 20:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “‘Kí ẹ ya ara yín sí mímọ́, kí ẹ sì di mímọ́,+ torí èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín. 8 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́, kí ẹ sì máa tẹ̀ lé wọn.+ Èmi ni Jèhófà, ẹni tó ń sọ yín di mímọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́