ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 31:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 “Bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ó ṣe pàtàkì pé kí ẹ pa àwọn sábáàtì mi mọ́,+ torí ó jẹ́ àmì láàárín èmi àti ẹ̀yin ní ìrandíran yín, kí ẹ lè mọ̀ pé èmi Jèhófà ló ń sọ yín di mímọ́.

  • Léfítíkù 21:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Kí o sọ ọ́ di mímọ́,+ torí òun ló ń gbé oúnjẹ Ọlọ́run rẹ wá. Kó jẹ́ mímọ́ sí ọ, torí èmi Jèhófà, tó ń sọ yín di mímọ́, jẹ́ mímọ́.+

  • 1 Tẹsalóníkà 5:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Kí Ọlọ́run àlàáfíà fúnra rẹ̀ sọ yín di mímọ́ pátápátá. Kí ẹ̀mí àti ọkàn* àti ara ẹ̀yin ará, tó dára ní gbogbo ọ̀nà, jẹ́ aláìlẹ́bi nígbà tí Olúwa wa Jésù Kristi bá wà níhìn-ín.+

  • 2 Tẹsalóníkà 2:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Síbẹ̀, ó di dandan fún wa láti máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nígbà gbogbo nítorí yín, ẹ̀yin ará tí Jèhófà* nífẹ̀ẹ́, torí pé àtìbẹ̀rẹ̀ ni Ọlọ́run ti yàn yín+ fún ìgbàlà nípa fífi ẹ̀mí rẹ̀ sọ yín di mímọ́+ àti nípa ìgbàgbọ́ yín nínú òtítọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́