Ẹ́kísódù 30:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 “Kí o ṣe pẹpẹ kan láti máa fi sun tùràrí;+ igi bọn-ọ̀n-ní ni kí o fi ṣe é.+ Ẹ́kísódù 30:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kí o gbé e síwájú aṣọ ìdábùú tó wà nítòsí àpótí Ẹ̀rí,+ níwájú ìbòrí tó wà lórí Ẹ̀rí, níbi tí màá ti pàdé rẹ.+
6 Kí o gbé e síwájú aṣọ ìdábùú tó wà nítòsí àpótí Ẹ̀rí,+ níwájú ìbòrí tó wà lórí Ẹ̀rí, níbi tí màá ti pàdé rẹ.+