ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 32:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Ní ọjọ́ kejì, Mósè sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ̀ṣẹ̀ ńlá lẹ dá, màá sì gòkè tọ Jèhófà lọ báyìí, kí n wò ó bóyá mo lè bá yín wá nǹkan ṣe sí ẹ̀ṣẹ̀ tí ẹ dá.”+

  • Léfítíkù 16:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “Ẹnì kankan ò gbọ́dọ̀ sí nínú àgọ́ ìpàdé látìgbà tó bá ti wọlé lọ ṣe ètùtù ní ibi mímọ́ títí yóò fi jáde. Kó ṣe ètùtù fún ara rẹ̀ àti ilé rẹ̀+ àti gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì.+

  • Nọ́ńbà 15:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Kí àlùfáà ṣe ètùtù fún gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n á sì rí ìdáríjì,+ torí pé àṣìṣe ni, wọ́n ti mú ọrẹ àfinásun wá fún Jèhófà, wọ́n sì ti mú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ wọn wá síwájú Jèhófà nítorí àṣìṣe wọn.

  • Éfésù 1:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ipasẹ̀ ìràpadà tó fi ẹ̀jẹ̀ ọmọ rẹ̀ san ni a fi rí ìtúsílẹ̀,+ bẹ́ẹ̀ ni, ìdáríjì àwọn àṣemáṣe wa,+ nítorí ọlá inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀.

  • Hébérù 2:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Bákan náà, ó ní láti dà bí “àwọn arákùnrin” rẹ̀ ní gbogbo ọ̀nà,+ kó lè di àlùfáà àgbà tó jẹ́ aláàánú àti olóòótọ́ nínú àwọn ohun tó jẹ mọ́ ti Ọlọ́run, kó lè rú ẹbọ ìpẹ̀tù*+ fún ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́