Ìṣe 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní ọjọ́ Àjọyọ̀ Pẹ́ńtíkọ́sì,+ gbogbo wọn wà níbì kan náà, bí àjọyọ̀ náà ṣe ń lọ lọ́wọ́.